Lyrics Orin D’owo.lrc K1 De Ultimate
[id: snpqtmaq]
[ar: K1 De Ultimate]
[al: Flavours, Vol. 1]
[ti: Orin D’owo]
[length: 09:08]
[00:33.21]Orin d’owó,orin dolà lo jẹ un wa dúpẹ o
[00:36.99]Orin d’owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d’owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá)
[00:57.22]Al’orin d’owó,orin dolà lo jẹ un wa dúpẹ o
[01:02.44]Orin d’owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d’owó orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá)
[01:17.28]Bi isẹ ba ti l’alubarika opẹ lo yẹ ki eru o da o
[01:21.26]Orin d’owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d’owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá)
[01:36.93]Àní bi isẹ ba ti l’alubarika ijó ló yẹ kẹrú ojó
[01:40.13]Orin d’owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d’owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá)
[01:58.28]Olú ayé fuji mo gbe eré ta wi de o
[02:05.10]Ọlọhun lo s’ọlà fuji bo ti rí ọ
[02:07.61]Ayinde Wasiu ẹrú ń dúpẹ’
[02:11.93]Bo ba wa dúpẹ ore agbà mi si ó
[02:14.57]Amuda wa sukura mo dúpẹ-dúpẹ o
[02:21.47]Gbogbo àwọn to tin lu fuji lati ijọ rí
[02:26.30]La t’ayé aji saari,aye aji wéré
[02:30.63]Ko to wa dori fuji ti isẹyin o
[02:45.39]Bi isẹ ba ti l’alubarika ijo ló yẹ k’ẹrú ojó
[02:49.38]Orin d’owó orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá
[02:56.36]Ìbà Sikiru mi ọmọ Abiba l’ọdọfin area
[03:00.34]Ìbà Ajadi Ganiyu l’oluwọlé
[03:02.94]Àwọn to kọ lu fuji lati aji wéré
[03:07.94]Ayinde Muniru ọmọ Mayegun
[03:10.57]Kao Aminu,Saka Laigbade mo la ó pe o
[03:13.95]Mufu fuji la wà atí Ayinde the law,l’akarawu area
[03:21.30]Ajadi lawa l’ewé iná o
[03:23.49]Jibowu Barrister,Kasali Alani mi yọmi
[03:35.03]Abinuwaye Basiru,Late Dauda mi Akanmu epo
[03:43.86]Epo àkàrà n’ibadan ọ’run ẹ re
[03:53.21]Akande Monsuru
[03:59.17]Kótó wa dorí Agbaje lọla mi Barry Wonder mi o
[04:04.29]Doctor Sikiru mi Ayinde Ade o
[04:08.81]Barusati mí Ìbà ẹ ni mo se ó
[04:13.18]Agbaje l’ọlá dèdẹgò ori ẹ sa l’ere tiyi padà
[04:20.30]Ayinla Kollinton baba latika
[04:24.46]Kebe Kwara mi ibà ni mo se ó
[04:29.24]Adio Fatai,Ogidan Ololaaju
[04:33.46]Ayinde Rahimi Bokotẹ
[04:37.98]Akani Ramoni mi Abiodun
[04:42.48]Hajji Lao Azeez l’agege ó
[04:46.95]Iyanda Sawaba mí ewé nla ó
[04:51.47]Akangbe Waheed ati Famusi mi Alamu aye ó
[04:57.88]Ati Kabaka ní Ilorin afonja ó
[05:02.28]Ati Sakariyau mí Danfo ó
[05:06.33]Emi ọba fuji lo ma ń kí yín ó
[05:10.74]K1 De Ultimate,akanda elédùmarè t’ayé nfẹ ó
[05:17.59]Ẹ’yin to ń bọ’ lẹ’yìn kẹ kí ará iwaju
[05:22.06]Ará iwaju oni re lẹ o
[05:26.53]A ó se fuji yi là fi l’owo lọ’wọ
[05:28.48]A ó se fuji yi là l’owo lọ’wọ’ (a ó se fuji yi là l’owo lọ’wọ)
[05:42.32]A ó se fuji yi là l’owo lọ’wọ
[05:44.66]A ó se fuji yi là l’owo lọ’wọ (a ó se fuji yi là l’owo lọ’wọ)
[05:52.41]Walahi talahi Ayinde ó,mo f’ọlọhun búra ọrọ ni
[06:02.88]Walahi talahi Ayinde ó,mo tún f’ọlọhun búra ọrọ ni
[06:06.94]Ẹni má báwa du ọrọ yí o,a de Mecca awa le
[06:12.36]Ọrọ yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o a ní tira tó dájú
[06:26.86]Walahi talahi Ayinde ó
[06:28.72]Ẹni ma báwa dù ọ’rọ’ yí o,a ní tira tó gboju
[06:34.20]Ọrọ yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o
[06:37.24]A de Mecca awá lé
[06:41.02](Yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin)
[06:54.08](Wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e, wadu e,wadu e)
[07:04.23]Motun f’ọlọhun búra Ayinde ó,Anọbi Muhamma
[07:07.33](Bàbá fa,bàbá fà,bàbá fa,bàbá fà,bàbá fa,bàbá fà, bàbá fa,bàbá fà,bàbá Fatimo)
[07:15.15]Eyi tí mo wi yẹn
[07:16.03](Ọrọ ní,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni)
[07:23.09](yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin,yasin)
[07:30.29]Million,million ní fi ó ojo ojúmọ’ ké
[07:33.69]Ọrọ yí ọ,ẹni ma bámi dù ọrọ yí o
[07:36.67]A ni sense to m’ori pe
[07:40.16]Òrò yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o
[07:43.03]A de Mecca awá lé
[07:49.14]Ẹ tún ban wípé bẹẹ noni (bẹẹ noni)
[07:59.94]Ani ẹ ban wípé bẹẹ noni o (bẹẹ noni)
[08:06.53]Ọlọhun Ọba ló ṣe àdéhùn yio (bẹẹ noni)
[08:12.58]Baba God ló ṣe àdéhùn yí o (bẹẹ noni)
[08:18.99]Pe òhun oni fí wa sílẹ fún ìyà jẹ o (bẹẹ noni)
[08:25.21]Ọlọhun Ọba mu ìlérí ẹ ṣẹ (bẹẹ noni)
[08:31.95]O ma se mu ìlérí ẹ ṣẹ ó (bẹẹ noni)
[08:37.60]Gbogbo oni fuji kẹ majo (bẹẹ noni)
[08:44.27]Kòní re ajo rẹyìn lọla Ọlọhun mi àmìn (bẹẹ noni)
[08:50.26]Ẹyin lon di àkùkọ ọmọ Gbolahan àbí (bẹẹ noni)
[08:56.08]Ẹyin lon di àkùkọ ọmọ Gbolahan Ayinde (bẹẹ noni)
[09:01.28]Ẹ wí pé bẹẹ noni o (bẹẹ noni)
[09:05.44]Year of Release: 2017